Tope Alabi – Iwo Lawa O Ma Bo & TY Bello lyrics

Tope Alabi – Iwo Lawa O Ma Bo & TY Bello lyrics : Tope Alabi, also known as Ore ti o common, and as Agbo Jesu is a Nigerian gospel singer, film music composer and actress. Tope Alabi was born on the 27th October, 1970 in Lagos State, Nigeria to Pa Joseph Akinyele Obayomi and Madam Agnes Kehinde Obayomi.

Tope Alabi – Iwo Lawa O Ma Bo Lyrics

WA MA Gbemi MI ninu
WA MA Gbemi lokan
WA MA Tami googo bi eni mutin olowo nla
WA MA romi siwaju
Romi so eyin to move ndun ninu ree
Kabiesi olowo orimi oooo
Wa ma gbemi ninu se
Wa ma gbe wa likon
Iwo loni ayo to kun inu wa
Wa ma gbemi ninu
Wa ma gbe wa ninu wa ma ti wa googo
Kin se bi eni fe subu sugbon bi eni fe dunnu
Idunu wa lo po ninu ree
Ayo igbala ree kun inu waa
Kabiesi oo awa ma gbe oo ga
Iwo to poo ni ipa ati agbara

Tope Alabi – Iwo Lawa O Ma Bo Video

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*